Báwo ni mo ṣe lè tún ọ̀rọ̀ aṣínà mi ṣe ní Deriv?
Tí o kò bá tíì fìdí àkọọ́lẹ̀ rẹ múlẹ̀, o lè ṣe àtúnṣe àwọn àlàyé ti ara ẹni wọ̀nyí nínú profaili rẹ, lábẹ́ abala “About you”:
Láti ṣe àtúnṣe sí ọ̀rọ̀ aṣínà yín:
- Ẹ lọ sí profaìlì yín
- Ẹ yan “Password” lábẹ́ abala Settings
- Ẹ máa gba OTP tí a óò fi ránṣẹ́ sí ímeèlì yín láti fi rí i dájú pé ẹ̀yin ni. Ẹ fi OTP náà sílẹ̀.
- Ẹ fi ọ̀rọ̀ aṣínà tuntun yín sílẹ̀






