Lọ sí àkóónú àkọ́kọ́

Deriv cTrader

Ẹ ṣe àfidàakọ àwọn ìṣòwò àwọn trader CFD tó ń ṣàṣeyọrí pẹ̀lú Copy Trading. Síwájú sí i, ẹ gba àǹfààní sí àwọn custom indicators tó ju 60 lọ, ìṣòwò nípasẹ̀ chart, àti àwọn ohun èlò ìṣúná àti synthetic tó lé ní 150 ní Deriv cTrader.

Kí nìdí tí ẹ fi ń ṣòwò pẹ̀lú Deriv cTrader

Ìjìnlẹ̀ òye ìṣòwò tí AI ń fi ipá sí

Ẹ mú àwọn ìlànà ìṣòwò yín sunwọ̀n sí i, ẹ ṣe àyẹ̀wò ọjà, àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ mìíràn pẹ̀lú ChatGPT tí a kó pọ̀ mọ́ ọn.

Onírúurú ohun ìṣòwò lórí pèpéle kan ṣoṣo

Ẹ ṣòwò forex, ìpín ìdókòwò, àwọn àtọ́ka ìpín ìdókòwò, àwọn owó crypto, ohun ọjà, àti Derived Indices ní ibì kan ṣoṣo.

Ìṣòwò ní wákàtí 24, ọjọ́ 7 lọ́sọ̀ọ̀sẹ̀

Ẹ ṣe Ìṣòwò Synthetic Indices nígbàkúgbà, kódà ní ìparí ọ̀sẹ̀ àti ní àwọn ọjọ́ ìsinmi.

QR code to download the app
Ẹ ṣàyẹ̀wò láti gbàá kalẹ̀

Android & iOS

Ẹ gba Deriv cTrader
Get it on Google PlayDownload on the Mac App StoreDownload for WindowsDownload on the App StoreTrade on Web browser

Copy trading lọ́nà tiyín

Ẹ ṣàkóso ewu yín nípa pínpín owó yín sí onírúurú ọgbọ́n ìṣòwò.

Ojú ìwọlé tó rọrùn láti lóye

Ẹ jàǹfààní ọ̀nà rírọrùn láti lo fún ìṣòwò àti ìyàwòrán, tí àwọn tó jẹ́ tuntun àti àwọn tí ó ní ìrírí nínú ìṣòwò lè gbádùn.

Ẹ mọ̀ nípa àwọn margin ìṣòwò yín

Àwọn àtòjọ tí ó wúlo níbi tí ẹ ti lè mọ bí margin ohun ọjà kọ̀ọ̀kan ṣe ń kan ìṣòwò yín kí ẹ tó fi í sílẹ̀.

Copy trading lọ́nà tiyín

Copy trading lọ́nà tiyín

Ẹ ṣàkóso ewu yín nípa pínpín owó yín sí onírúurú ọgbọ́n ìṣòwò.

Ojú ìwọlé tó rọrùn láti lóye

Ojú ìwọlé tó rọrùn láti lóye

Ẹ jàǹfààní ọ̀nà rírọrùn láti lo fún ìṣòwò àti ìyàwòrán, tí àwọn tó jẹ́ tuntun àti àwọn tí ó ní ìrírí nínú ìṣòwò lè gbádùn.

Ẹ mọ̀ nípa àwọn margin ìṣòwò yín

Ẹ mọ̀ nípa àwọn margin ìṣòwò yín

Àwọn àtòjọ tí ó wúlo níbi tí ẹ ti lè mọ bí margin ohun ọjà kọ̀ọ̀kan ṣe ń kan ìṣòwò yín kí ẹ tó fi í sílẹ̀.

Gbogbo àwọn ohun-ìní tí ẹ fẹ́ràn jùlọ ní ibì kan ṣoṣo

Ẹ ṣe ìṣòwò àwọn ohun ìní derived àti ti owó nínú àkáǹtì CFD kan ṣoṣo, láìnílò láti máa yí padà láàrín oríṣiríṣi àkáǹtì.

Copy trading ní Deriv cTrader

Ẹ ṣe copy trade ní Deriv cTrader nípa fífi orúkọ sílẹ̀ fún àwọn ìlànà àwọn akọṣẹ́mọṣẹ́ ní ìṣòwò pẹ̀lú owó kékeré. Ẹ wá ìlànà tó wu yín, kí ẹ sì fi í sílò sí àwọn ìṣòwò yín pẹ̀lú ìtẹ̀ bọ́tìn kan ṣoṣo.

Oríṣiríṣi ìlànà ìṣòwò

Ẹ yan láti inú àtòjọ àwọn olùpèsè ìlànà ìṣòwò kí ẹ sì rí ìlànà ìṣòwò tó bá a yín mu.

Ẹ̀yin ni ẹ ń ṣàkóso

Ẹ yan láti dá ìṣòwò dúró tàbí láti dáwọ́ dúró nínú olùpèsè ìlànà ìṣòwò nígbàkigbà tí ẹ bá fẹ́.

Àwọn irinṣẹ́ ìṣàkóso ewu

Dín àwọn ewu tí ó lè wà nínú àwọn ìlànà ìṣòwò tí ẹ yàn kù.

Àwọn Ìbéèrè Tí A Sábà Ń Béèrè Nípa Deriv cTrader

Copy trading jẹ́ kí ẹ lè ṣe copy àwọn ìṣòwò àwọn akọṣẹ́mọṣẹ́ ní ìṣòwò (tí à ń pè ní strategy providers) láìfọwọ́rọsowọ́pọ̀ ní àkókò gidi. Nígbà tí wọ́n bá ṣe ìṣòwò, àkáǹtì yín náà máa ṣe bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ — kò nílò ìkọlu ọwọ́ kankan.
Tí ẹ bá ní ìtàn àkọọ́lẹ̀ ìṣòwò tó dára, ẹ lè tẹ ìlànà yín jáde ní Deriv cTrader kí ẹ sì jẹ́ kí àwọn mìíràn dà á kọ́pà. Ẹ máa yan owó kọmíṣọ̀n tiyín fúnra yín, a ó sì san ẹ̀yin nígbà tí àwọn mìíràn bá tẹ̀lé àwọn ìṣòwò yín.
Àwọn tó ń pèsè ìlànà lè gba oríṣi owó mẹ́ta: ti ìṣe-rere, ti ìṣàkóso, àti ti bí iye ìṣòwò ṣe pọ̀ tó. Gẹ́gẹ́ bí ẹni tó ń ṣe Copy Trading, ẹ̀yin yóò san owó tí olùpèsè tí ẹ yàn ṣètò nìkan nítorí pé kò sí owó àfikún láti ọ̀dọ̀ Deriv.
Lẹ́yìn tí ọgbọ́n ìṣòwò yín bá ti bẹ̀rẹ̀ sí í ṣiṣẹ́, ẹ lè dúró, ṣàtúnṣe, tàbí yọ ọ́ kúrò nígbàkigbà láti orí dashboard Deriv cTrader yín. Ẹ tún lè ṣe àmójútó iṣẹ́ rẹ̀ àti ṣàtúnṣe ètò owó kọmíṣọ̀n yín nígbàkigbà tí ó bá yẹ.

Ẹ dara pọ̀ mọ́ àwọn oníṣòwò àgbáyé tó ju 3M lọ

Ẹ ṣí àkáǹtì láàrin ìṣẹ́jú díẹ̀, kí ẹ sì bẹ̀rẹ̀ sí ṣòwò àwọn ọjà àgbáyé — forex, àwọn ìpín ìdókòwò, àwọn àtọ́ka, àti àwọn mìíràn.

WhatsApp