Deriv P2P
Ẹ lo owó orílẹ̀-èdè yín láti fi owó sí àti láti yọ owó kúrò ní àkáǹtì Deriv yín. Iṣẹ́ peer-to-peer wa máa ń so yín pọ̀ mọ́ àwọn alájọṣòwò láti rán owó ní ààyè ìṣẹ́jú.

Bí a ṣe lè rí Deriv P2P
Ẹ gba app náà sílẹ̀
Ẹ ṣe ìgbàsọ̀kalẹ̀ Deriv P2P tààrà láti ibi ìtajà app ẹ̀rọ yín.

Ẹ ṣètò àkáǹtì ìròyìn yín
Ẹ wọlé sí àkáǹtì Deriv yín, ẹ parí ìfidámulẹ̀, kí ẹ sì dá orúkọ oyè yín sílẹ̀.

Ẹ bẹ̀rẹ̀ sí í sopọ̀
Ẹ bá àwọn ẹlẹgbẹ́ yín oníṣòwò sopọ̀ láti ṣe ìfisílé àti yíyọ owó.

*Wíwà Deriv P2P dá lórí orílẹ̀-èdè tí ẹ ń gbé.
Ìgbésẹ̀ mẹ́ta fún ìsanwó-sí-àkáǹtì àti yíyọ owó kíákíá
Step 1
Ẹ wá tàbí ẹ dá ipolówó kan
Ẹ yan iye tó dára jùlọ kí ẹ sì fi àṣẹ̀ ìbéèrè sílẹ̀, tàbí kí ẹ dá ìpolówó kan sílẹ̀ fún iye tí ẹ fẹ́.
Step 2
Ẹ fi ránṣẹ́ tàbí ẹ gba owó ìsanwó
Ẹ san owó náà fún alábàáṣepọ̀ nínú ìdúnàádúrà yín.
Step 3
Ẹ parí ìdúnàádúrà náà
Gbogbo ìbéèrè ìṣòwò ni kí ẹ parí àti fọwọ́ sí i láàrin wákàtí 1.


