

Ẹ mọ̀ sí i. Ẹ ṣòwò dáadáa.
Ẹ lo àwọn ẹ̀kọ́, àwọn ebook àti àwọn ìtọ́sọ́nà ọ̀fẹ́ láti Deriv Academy tó ń sọ ìdíjú ọjà di ìpinnu ìṣòwò tó yé kedere—ì báà jẹ́ ipele ìrírí yín.

Àwọn ẹ̀kọ́ fún gbogbo oníṣòwò
Ẹ tẹ̀síwájú ní ìwọ̀n agbára yín pẹ̀lú àwọn ẹ̀kọ́ jíjinlẹ̀ àti àwọn ìdánwò kúkúrú oníbáṣepọ̀ tí a ṣe láti ràn yín lọ́wọ́ láti gbé òye yín dé ipele tó ga jù.
Ẹ darapọ̀ mọ́ àwùjọ wa jákèjádò àgbáyé
Ẹ bá àwọn oníṣòwò kárí ayé sọ̀rọ̀ láti pààrọ̀ ojú ìwòye, ṣàyẹ̀wò àwọn portfolio, kí ẹ sì jèrè ìmọ̀ tó ṣeyebíye.
Àwọn ìtọ́sọ́nà ìṣòwò tí ẹ nílò
Ẹ lo àkójọ àwọn àpilẹ̀kọ wa tó ń pọ̀ sí i, tó rọrùn láti tẹ̀lé, tó ń ṣàlàyé àwọn èròǹgbà ìṣòwò pàtàkì àti àwọn irinṣẹ́ pèpéle.
Ìròyìn Ọjà
Ẹ máa gbọ́ àwọn ìtẹ̀sí ọjà tuntun, ìmọ̀ nípa ètò ìnáwó àti ìtúpalẹ̀ ìṣòwò ní Blog wa.
Àwọn ebook tó ń kọ́ òye
Láti àwọn àpẹẹrẹ ìtúpalẹ̀ ẹ̀rọ títí dé ìrònú ọkàn oníṣòwò, àwọn ebook wa ń ṣàlàyé àwọn èròǹgbà gidi àti ojútùú gidi fún ìdàgbàsókè ìṣòwò yín.
Àwọn ìtọ́sọ́nà fídíò ìṣòwò pàtàkì
Ẹ wo àwọn fídíò kúkúrú tó dojúkọ ọ̀rọ̀ kan, tó ń fi bí ẹ ṣe lè lo àwọn èròǹgbà àti bí ẹ ṣe lè lo àwọn pèpéle ìṣòwò wa hàn yín.
Àlàyé lórí ìṣòwò Options | Ìfihàn ní tààrà | Deriv Trader
Ẹ kọ́ bí a ṣe ń ṣòwò Digital Options lórí pèpéle Deriv Trader pẹ̀lú Vince Stanzione, oníṣòwò tó ní ìrírí púpọ̀ àti òǹkọ̀wé tí ìwé rẹ̀ ta jù lọ ní New York Times.
Bí a ṣe ń ṣòwò Volatility Indices lórí Deriv MT5 | Ìfihàn ní tààrà
Ẹ kọ́ lọ́dọ̀ Vince Stanzione, oníṣòwò tó ní ìrírí àti òǹkọ̀wé tí ìwé rẹ̀ ta jù lọ ní New York Times, bó ṣe ń pín ìmọ̀ lórí bí a ṣe ń lo Deriv MT5 láti ṣòwò Volatility Indices.
Bí a ṣe ń ṣòwò Bitcoin lórí Deriv MT5 | Ìfihàn ní tààrà
Ẹ ṣàwárí àṣírí ìṣòwò Bitcoin tó yọrí sí rere pẹ̀lú Vince Stanzione—oníṣòwò tó ní ìrírí àti òǹkọ̀wé tí ìwé rẹ̀ ta jù lọ ní New York Times

Ẹ ní ìmọ̀ pípé nípa àwọn ọ̀rọ̀ ìṣòwò
Ẹ mọ àwọn ọ̀rọ̀ ìṣòwò tí ó yẹ kí ẹ mọ̀ nínú Glossary wa.









