Lọ sí àkóónú àkọ́kọ́

Báwo ni mo ṣe lè ṣàkóso àwọn àdánù mi pẹ̀lú Deriv Bot?

Tí o kò bá tíì fìdí àkọọ́lẹ̀ rẹ múlẹ̀, o lè ṣe àtúnṣe àwọn àlàyé ti ara ẹni wọ̀nyí nínú profaili rẹ, lábẹ́ abala “About you”:

1. Ẹ ṣẹ̀dá àwọn fáríẹ́bù (variables) tí ó tẹ̀lé e yìí, kí ẹ sì fi wọ́n sí abẹ́ Run once at start:

Tí o bá ti fìdí àkọọ́lẹ̀ rẹ múlẹ̀ tẹ́lẹ̀, tí o sì fẹ́ ṣe àtúnṣe àdírẹ́sì rẹ, o ní láti kàn sí ìrànlọ́wọ́ láti yí i padà.

Nínú profaili rẹ, o tún lè ṣàyẹ̀wò ipò àti ṣe àtúnṣe:

2. Ẹ ṣètò àwọn Purchase conditions. Nínú àpẹẹrẹ yìí, bot yín yóò rà ọwọ́-ẹ̀rí Rise nígbà tí ó bá bẹ̀rẹ̀ àti lẹ́yìn tí ọwọ́-ẹ̀rí kan bá parí.

3. Ẹ lo bulọ́ọ̀kù lójíkì (logic block) láti ṣàyẹ̀wò bóyá Total profit/loss kọjá iye owó Stop loss threshold. Ẹ lè rí fáríẹ́bù Total profit/loss náà ní abẹ́ Analysis > Stats lórí Blocks menu tí ó wà ní apá òsì. Bot yín yóò máa tẹ̀síwájú láti máa ra àwọn ọwọ́-ẹ̀rí tuntun títí tí iye owó Total profit/loss yóò fi kọjá iye owó Stop loss threshold.

Ṣé o ṣì nílò ìrànlọ́wọ́?

WhatsApp