Lọ sí àkóónú àkọ́kọ́

Kí ni àwọn ìyàtọ̀ pàtàkì láàrín àwọn pèpéle digital options àti CFD yín?

Tí o kò bá tíì fìdí àkọọ́lẹ̀ rẹ múlẹ̀, o lè ṣe àtúnṣe àwọn àlàyé ti ara ẹni wọ̀nyí nínú profaili rẹ, lábẹ́ abala “About you”:

Deriv MT5 ń pèsè ìṣòwò CFD lórí irú àwọn ohun ìní kan náà, níbi tí ẹ lè ṣí àwọn ipò ìṣòwò pẹ̀lú Leverage, tí èrè tí ẹ lè jẹ́ yóò sì di mímọ̀ nígbà tí ẹ bá ti ì tí àwọn ipò ìṣòwò yín. Ó léwu ju ìṣòwò digital options lọ, nítorí pé bí ẹ lè jẹ́rè púpọ̀ tí ọjà bá yí padà sí ojúrere yín, bẹ́ẹ̀ náà ni ẹ lè pàdánù púpọ̀ bí kò bá rí bẹ́ẹ̀.

Ṣé o ṣì nílò ìrànlọ́wọ́?

WhatsApp