Báwo ni mo ṣe lè wọlé sí Partner's Hub?
- Ẹ lọ sí ojú ìwé Partners page wa.
- Ẹ tẹ Login ní òkè ọ̀tún.
- Ẹ tẹ àwọn ìsọfúnni ìwọlé yín sínú.
- Àṣàyàn: Ẹ lè ṣe bukimáàkì Partner's Hub kí ó rọrùn fún yín láti wọlé sí i nígbà mìíràn.
Tí ẹ bá ti ní àkáǹtì ìṣòwò Deriv tẹ́lẹ̀, ẹ tún lè lo àwọn ìsọfúnni ìwọlé kan náà láti wọlé.
Àkíyèsí: Àwọn ìsọfúnni ìwọlé àkáǹtì ìṣòwò Deriv yín àti àwọn ìsọfúnni ìwọlé Partner's Hub yín gbọ́dọ̀ jọra kí ẹ bàa lè wọlé sí dashboard Partner.