Níbo ni mo ti lè wo àwọn ìsọfúnni nípa àwọn API token mi?
- Ẹ wọlé sí api.deriv.com nípa lílo àkáǹtì Deriv yín.
- Ẹ lọ sí Dashboard.
- Ẹ lọ sí tab API Token Manager; ẹ óò rí àtòjọ gbogbo àwọn API token tí ó ní ìsopọ̀ pẹ̀lú àkáǹtì yín, pẹ̀lú àwọn ìsọfúnni wọn bí orúkọ token, irúfẹ́ àkáǹtì, àyè iṣẹ́ token, àti ìgbà tí a kẹ́yìn lò ó.